PEACE/COMFORT

PEACE/COMFORT
Peace is a vital ingredient for the attainment of long life and vitality of life. In an atmosphere without peace, nothing can be achieved. Therefore, efforts must be made in order to make sure that peace is attained. At African Heritage, we shall assist you at making sure that no stone is left unturned as far as good health and vitality of life is concerned. Below are two stanzas of Ifá in ìdin-‘Gbè, which underscores the importance of peace in the life of humans:
Asáká ní gbàro
Ọ̀gbèngbè ńgerè
Ká fèyí sègbè baba Adéyẹ́mọ
Dífá fún Ọ̀rúnmìlà
Wọ́n ní baba ó nii ni ìsinmi làyé
Ẹbọ ni wọ́n ní kó ṣe
Ó gbẹ́bọ, ó rúbọ
Njẹ́, àparò lawo jẹ̀ o
Awo o lọ́rùn gbẹ̀sẹ̀

Translation:
Asáká ní gbàro (alias)
Ọ̀gbèngbè ńgerè (alias)
Ká fèyí sègbè baba Adéyẹ́mọ (alias)
They were the awo who cast Ifá for Ọ̀rúnmìlà
When the enemies declared that he would not have comfort in life
He was advised to offer sacrifice
Behold, it is àparò, bush fowl that Awo has eaten
The who is not going to be bankrupt

Ẹyẹ́lẹ́ lójí ní kùtùkùtù
Ló fomi wúrú san ẹsẹ̀ nù
Dífá fún Ọlọ́fin Aayé ò rójú
Ẹbọ ni wọ́n ni ko waa ṣe
Ó gbẹ́bọ, ó rúbọ
Àwa róju, àwa rááyè
Àwa ríhun wa yoo nù

Translation:
The pigeon woke up in the morning
And washed off its legs with the water of gold
This was the message of Ifá for Ọlọ́fin, the one who was not comfortable in life
He was advised to offer ẹbọ
He complied
Yes, we have had comfort and also have the convenience
We have seen our lost thing